Alágbádá Iná
The one with the garment of fire
Àṣẹ̀dá Ọ̀rún
The one who created the heavens
Ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀ létí òkún
The mighty one at the edge of the sea
Ọba àwọn ọba
King of kings
Mo tẹríba fún ọ
I bow to you
Títí ayé ni mo ma sìn ọ́
I will worship you for eternity
Published by